Wednesday, April 18, 2012

Yemaya, Generous and Healing Mother

Mo juba awo Yemoja.
Iwo ni Ayaba Iya.
Iwo ni Iya Orisha.
Iwo ni Inu Iye Odidi.
Iwo ni Ifihan Ti Abo Ase.
Iwo ni Inu Aiye.
Iwo ni Orisha Obinrin Okun Nla ati Odo.
Iwo ni Oluwa Awo Ti Abo Ipilese.

I humble myself before the mystery of Yemoja.
You are the Queen of Mothers.
You are the Mother of the Orisha.
You are the Womb of all Life.
You are the Feminine Manifestation of the Ase.
You are the Womb of the World.
You are the Goddess of the Oceans and Rivers.
You are the Owner of the Mystery of the Feminine Principle.

 Prayer via ifeifa.org